Main content
Ṣé lóòótọ́ ni jẹ́ ètò tí ó ń dáhùn àwọn ìbéèrè lórí àwọn ǹkan tó bá rú wá lójú láwùjọ. Eléyìí lè jẹ́ lórí ọ̀rọ̀ ìlera, ìṣúná, èèwọ̀, àṣà ilẹ̀ Yorùbá àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn oríṣiríṣi akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ máa ṣàlàyé kíkún lórí àwọn ohun tó bá ru ni lójú. Kókó ètò yìí ni láti pèsè aláyè tó pé lórí onírúurú ìbéèrè fún àwọn olùgbọ́.